1 Kọ́ríńtì 1:14 BMY

14 Inú mi dún púpọ̀ pé èmi kò tẹ ẹnikẹ́ni nínú yín bọmi yàtọ̀ sí Kírísípù àti Gáíù.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:14 ni o tọ