1 Kọ́ríńtì 1:16 BMY

16 (Bẹ́ẹ̀ ni, mo tún tẹ ìdílé Sítéfánà bọmi; lẹ́yìn èyí, èmí kò rántí pé mo tẹ ẹnikẹ́ni bọmi mọ́ níbikíbi).

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:16 ni o tọ