1 Kọ́ríńtì 1:30 BMY

30 Nítorí rẹ̀ ni ẹ̀yin ṣe wà nínú Kírísítì Jésù ẹni ti ó já sí ọgbọ́n fún wa láti ọ̀dọ̀ Ọlọ́run—èyi ń ni, òdodo, ìwà mímọ́ àti ìràpadà wa.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 1

Wo 1 Kọ́ríńtì 1:30 ni o tọ