1 Kọ́ríńtì 10:7 BMY

7 Kí ẹyin má ṣe sin ère òrìṣà gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣe; gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ pé, “Àwọn ènìyàn náà jókòó láti jẹ àti láti mu, wọ́n sì dìde dúró láti jó.”

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 10

Wo 1 Kọ́ríńtì 10:7 ni o tọ