1 Kọ́ríńtì 11:6 BMY

6 Ṣùgbọ́n tí obìnrin bá kọ̀ láti bo orí rẹ̀, ẹ jẹ́ kí ó gé irun rẹ̀. Bí ó bá sì jẹ́ nǹkan ìtìjú fún un làti gé irun orí rẹ́, nígbà náà kí ó fi gèlè bo orí rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 11

Wo 1 Kọ́ríńtì 11:6 ni o tọ