1 Kọ́ríńtì 13:11 BMY

11 Nígbà tí mó wà ni èwe, èmi á máa sọ̀rọ̀ bi èwe, èmi a máa mòye bí èwe, emí a máa gbèrò bí èwe. Ṣùgbọ́n nígbà tí mó di ọkùnrin tán, mo fi ìwà èwe sílẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:11 ni o tọ