1 Kọ́ríńtì 13:13 BMY

13 Ǹjẹ́ nísinsìnyìí àwọn nǹkan mẹ́ta wọ̀nyí dúró: ìgbàgbọ́, ìrètí, àti ìfẹ́. Ṣùgbọ́n èyí tí o tóbi jù nínú wọn ni ìfẹ́.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 13

Wo 1 Kọ́ríńtì 13:13 ni o tọ