35 Bí wọ́n bá sì fẹ́ mọ̀ nípa ohunkóhun, kí wọn bèèrè lọ́wọ́ ọkọ wọn ní ilé; nítorí ohun ìtìjú ni fún àwọn obìnrin láti máa sọ̀rọ̀ nínú ìjọ.
Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 14
Wo 1 Kọ́ríńtì 14:35 ni o tọ