1 Kọ́ríńtì 14:7 BMY

7 Bẹ́ẹ̀ ní pẹ̀lú àwọn nǹkan tí kò ní ẹ̀mí tí ń dún, ìba à ṣe fèrè tàbí dùùrù bí kò ṣe pé ìyàtọ̀ bá wà nínú wọn, a ó tí ṣe mọ ohùn tí fèrè tàbí tí dùùrù ń wí?

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 14

Wo 1 Kọ́ríńtì 14:7 ni o tọ