1 Kọ́ríńtì 15:24 BMY

24 Nígbá náà ni òpín yóò dé, nígbà tí ó bá ti fi ìjọba fún Ọlọ́run Baba, nígbà tí ó bá pá gbogbo àṣẹ àti gbogbo ọlá àti agbára run.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 15

Wo 1 Kọ́ríńtì 15:24 ni o tọ