1 Kọ́ríńtì 15:32 BMY

32 Kí a wí bí ènìyàn, bí mo bá ẹranko jà ní Éfésù, àǹfàání kín ni ó jẹ́ fún mi? Bí àwọn òkú kò bá jínde,“Ẹ jẹ́ kí a máa jẹ kí á máa mú;nítorí ní ọlá ni àwa ó kú.”

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 15

Wo 1 Kọ́ríńtì 15:32 ni o tọ