1 Kọ́ríńtì 15:41 BMY

41 Ọ̀tọ̀ ni ògo ti òòrùn, ọ̀tọ̀ ni ògo ti òṣùpá, ọ̀tọ̀ sì ni ògo ti ìràwọ̀; ìràwọ̀ sá yàtọ̀ sí ìràwọ̀ ni ògo.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 15

Wo 1 Kọ́ríńtì 15:41 ni o tọ