1 Kọ́ríńtì 15:44 BMY

44 A gbìn ín ni ara ti ọkàn, a sì jí i dìde ni ara ti ẹ̀mí.Bí ara tí ọkàn bá ń bẹ, ara ẹ̀mí náà sì ń bẹ.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 15

Wo 1 Kọ́ríńtì 15:44 ni o tọ