1 Kọ́ríńtì 15:58 BMY

58 Nítorí náà ẹ̀yín ará mi olùfẹ́ẹ̀ ẹ máa dúró ṣinṣin, láìyẹsẹ̀, kí ẹ máa pọ̀ si í ní iṣẹ́ Olúwa nígbà gbogbo, níwọn bí ẹyin ti mọ̀ pé iṣẹ́ yin kì í ṣe asán nínú Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 15

Wo 1 Kọ́ríńtì 15:58 ni o tọ