1 Kọ́ríńtì 4:12 BMY

12 Tí a ń fi ọwọ́ ara wa ṣiṣẹ́, wọn ń gàn wa, àwa ń súre, wọn ń ṣe inúnibíni sí wa, àwa ń forítì i.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 4

Wo 1 Kọ́ríńtì 4:12 ni o tọ