1 Kọ́ríńtì 7:38 BMY

38 Bẹ́ẹ̀ sì ní ẹni tí ó fi wúndíá ọmọbìnrin fún ni ní ìgbéyàwó, ó ṣe rere; ṣùgbọ́n ẹni tí kò fi fún ni ní ìgbéyàwó ṣe rere jù lọ.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 7

Wo 1 Kọ́ríńtì 7:38 ni o tọ