1 Kọ́ríńtì 9:27 BMY

27 Ṣùgbọ́n èmi ń ń kó ara mi níjànu, mo sì n mú un wá sí abẹ́ ìtẹríba, pé lẹ́yìn tí mo ti wàásù fún áwọn ẹlòmíràn, nítorí ohunkóhun, kí èmi fún rara mi má se di ẹni ìtanú fún ẹ̀bùn náà.

Ka pipe ipin 1 Kọ́ríńtì 9

Wo 1 Kọ́ríńtì 9:27 ni o tọ