Àwọn Hébérù 10:5 BMY

5 Nítorí náà nígbà tí Kísítì wá sí ayé, ó wí pé,“Ìwọ kò fẹ́ ẹbọ àti ọrẹ,ṣùgbọ́n ara ni ìwọ ti pèsè fún mi;

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 10

Wo Àwọn Hébérù 10:5 ni o tọ