Àwọn Hébérù 12:26 BMY

26 Ohùn ẹni ti o mi ayé nígbà náà: ṣùgbọ́n nísinsin yìí o ti ṣe ìlérí, wí pé, “Lẹ́ẹ̀kan sí i èmi ki yóò mi kìkì ayé nìkan, ṣùgbọ́n ọ̀run pẹ̀lú.”

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 12

Wo Àwọn Hébérù 12:26 ni o tọ