Àwọn Hébérù 13:18 BMY

18 Ẹ máa gbàdúrà fún wa: Nítorí àwa gbàgbọ́ pé àwa ni ẹ̀rí ọkàn rere, a sì ń fẹ́ láti máa hùwà títọ́ nínú ohun gbogbo.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13

Wo Àwọn Hébérù 13:18 ni o tọ