Àwọn Hébérù 4:6 BMY

6 Nítorí náà bí ó tí jẹ́ pé, ó ku kí àwọn kan wọ inú rẹ̀, àti àwọn tí a tí wàásù ìyìn rere náà fún ní ìṣáajú kò wọ inú rẹ̀ nítorí àìgbọ́ràn:

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4

Wo Àwọn Hébérù 4:6 ni o tọ