Àwọn Hébérù 7:25 BMY

25 Nítorí náà ó sì le gbà wọ́n là pẹ̀lú títí dé òpin, ẹni tí ó bá tọ Ọlọ́run wá nipasẹ̀ rẹ̀, nítorí tí o ń bẹ láàyè títí láé láti máa bẹ̀bẹ̀ fún wọn.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 7

Wo Àwọn Hébérù 7:25 ni o tọ