Àwọn Hébérù 7:26 BMY

26 Nítorí pé irú olórí àlùfáà bẹ́ẹ̀ ni o yẹ wá, mímọ́, àìlẹ́gàn, àìléèérí, tí a yà sọ́tọ̀ kúrò láàrin àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbéga ju àwọn ọ̀run lọ;

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 7

Wo Àwọn Hébérù 7:26 ni o tọ