Ẹsira 4:21 BM

21 Nítorí náà, ẹ pàṣẹ pé kí wọ́n dáwọ́ iṣẹ́ náà dúró títí wọn yóo fi gbọ́ àṣẹ mìíràn láti ọ̀dọ̀ mi.

Ka pipe ipin Ẹsira 4

Wo Ẹsira 4:21 ni o tọ