Ẹsira 4:22 BM

22 Ẹ má ṣe fi iṣẹ́ náà jáfara, nítorí tí ẹ bá fi falẹ̀, ó lè pa ọba lára.”

Ka pipe ipin Ẹsira 4

Wo Ẹsira 4:22 ni o tọ