Ẹsira 6:1 BM

1 Dariusi ọba pàṣẹ pé kí wọ́n wádìí fínnífínní ninu àwọn ìwé àkọsílẹ̀ tí ó wà ní ààfin, ní ilẹ̀ Babiloni.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:1 ni o tọ