Ẹsira 8:12 BM

12 Ninu àwọn ọmọ Asigadi, Johanani, ọmọ Hakatani, ni olórí;orúkọ aadọfa (110) eniyan ni wọ́n kọ sílẹ̀ pẹlu rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹsira 8

Wo Ẹsira 8:12 ni o tọ