Hosia 1:3 BM

3 Hosia bá lọ fẹ́ iyawo kan tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Gomeri, ọmọ Dibulaimu. Gomeri lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan fún un.

Ka pipe ipin Hosia 1

Wo Hosia 1:3 ni o tọ