Hosia 11:6 BM

6 A óo fi idà run àwọn ìlú wọn, irin ìdábùú ìlẹ̀kùn bodè wọn yóo ṣẹ́, a óo sì pa wọ́n run ninu ibi ààbò wọn.

Ka pipe ipin Hosia 11

Wo Hosia 11:6 ni o tọ