Hosia 5:5 BM

5 Ìgbéraga Israẹli hàn kedere lójú rẹ̀; Efuraimu yóo kọsẹ̀, yóo sì ṣubú ninu ìwà burúkú rẹ̀, Juda náà yóo ṣubú pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Hosia 5

Wo Hosia 5:5 ni o tọ