Hosia 5:6 BM

6 Wọn yóo mú mààlúù ati aguntan wá, láti fi wá ojurere OLUWA, ṣugbọn wọn kò ní rí i; nítorí pé, ó ti fi ara pamọ́ fún wọn.

Ka pipe ipin Hosia 5

Wo Hosia 5:6 ni o tọ