Heberu 1:2 BM

2 Ní àkókò ìkẹyìn yìí, ó wá bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ rẹ̀, ẹni tí ó fi ṣe àrólé ohun gbogbo, nípasẹ̀ ẹni tí ó dá ayé.

Ka pipe ipin Heberu 1

Wo Heberu 1:2 ni o tọ