Heberu 1:6 BM

6 Ṣugbọn nígbà tí ó mú àkọ́bí rẹ̀ wọ inú ayé, ohun tí ó sọ ni pé,“Kí gbogbo àwọn angẹliỌlọrun foríbalẹ̀ fún un.”

Ka pipe ipin Heberu 1

Wo Heberu 1:6 ni o tọ