Heberu 10:11 BM

11 Àwọn alufaa a máa dúró lojoojumọ láti ṣe iṣẹ́ ìsìn wọn, láti máa rú ẹbọ kan náà tí kò lè kó ẹ̀ṣẹ̀ lọ nígbàkúùgbà.

Ka pipe ipin Heberu 10

Wo Heberu 10:11 ni o tọ