Heberu 10:27 BM

27 Ohun tí ó kù ni pé kí á máa retí ìdájọ́ pẹlu ìpayà ati iná ńlá tí yóo pa àwọn ọ̀tá Ọlọrun.

Ka pipe ipin Heberu 10

Wo Heberu 10:27 ni o tọ