Heberu 10:39 BM

39 Ṣugbọn àwa kò sí ninu àwọn tí wọn ń fà sẹ́yìn sí ìparun. Ṣugbọn àwa ní igbagbọ, a sì ti rí ìgbàlà.

Ka pipe ipin Heberu 10

Wo Heberu 10:39 ni o tọ