Heberu 11:19 BM

19 Èrò rẹ̀ ni pé Ọlọrun lè tún jí eniyan dìde ninu òkú. Nítorí èyí, àfi bí ẹni pé ó tún gba ọmọ náà pada láti inú òkú.

Ka pipe ipin Heberu 11

Wo Heberu 11:19 ni o tọ