Heberu 12:7 BM

7 Ẹ níláti faradà á bí ìtọ́sọ́nà. Ọlọrun mú yín bí ọmọ ni. Nítorí ọmọ wo ni ó wà tí baba rẹ̀ kò ní tọ́ sọ́nà?

Ka pipe ipin Heberu 12

Wo Heberu 12:7 ni o tọ