Heberu 13:16 BM

16 Ẹ má gbàgbé láti máa ṣe rere, kí ẹ sì máa fún àwọn ẹlòmíràn ninu àwọn ohun ìní yín. Irú ẹbọ yìí ni inú Ọlọrun dùn sí.

Ka pipe ipin Heberu 13

Wo Heberu 13:16 ni o tọ