Heberu 13:18 BM

18 Ẹ máa gbadura fún wa. Ó dá wa lójú pé ọkàn wa mọ́. Ohun tí ó dára ni a fẹ́ máa ṣe nígbà gbogbo.

Ka pipe ipin Heberu 13

Wo Heberu 13:18 ni o tọ