Heberu 6:13 BM

13 Nítorí nígbà tí Ọlọrun ṣe ìlérí fún Abrahamu, ara rẹ̀ ni ó fi búra nígbà tí kò sí ẹnìkan tí ó tóbi bíi rẹ̀ tí ìbá fi búra.

Ka pipe ipin Heberu 6

Wo Heberu 6:13 ni o tọ