Heberu 6:17 BM

17 Ní ọ̀nà kan náà, nígbà tí Ọlọrun fẹ́ fihàn gbangba fún àwọn ajogún ìlérí wí pé èrò òun kò yipada, ó ṣe ìlérí, ó sì fi ìbúra tì í.

Ka pipe ipin Heberu 6

Wo Heberu 6:17 ni o tọ