Heberu 7:14 BM

14 Nítorí ó hàn gbangba pé láti inú ẹ̀yà Juda ni Oluwa wa ti wá. Mose kò sì sọ ohunkohun tí ó jẹ mọ́ iṣẹ́ alufaa nípa ẹ̀yà yìí.

Ka pipe ipin Heberu 7

Wo Heberu 7:14 ni o tọ