Heberu 7:24 BM

24 Ṣugbọn ní ti Jesu, ó wà títí. Nítorí náà kò sí ìdí tí a óo fi tún yan alufaa mìíràn dípò rẹ̀.

Ka pipe ipin Heberu 7

Wo Heberu 7:24 ni o tọ