Heberu 7:8 BM

8 Ati pé, àwọn ọmọ Lefi tí wọn ń gba ìdámẹ́wàá, ẹni tí yóo kú ni wọ́n. Ṣugbọn Ìwé Mímọ́ sọ nípa Mẹlikisẹdẹki pé ó wà láàyè.

Ka pipe ipin Heberu 7

Wo Heberu 7:8 ni o tọ