11 Kì yóo sí ìdí tí ẹnìkan yóo fi kọ́ aládùúgbò rẹ̀ tabi arakunrin rẹ̀, pé,‘Mọ Oluwa.’Nítorí pé gbogbo wọn ni wọn óo mọ̀ mí,ohun tí ó ṣẹ̀ láti orí àwọn mẹ̀kúnnù inú wọn títí dé orí àwọn eniyan pataki pataki.
Ka pipe ipin Heberu 8
Wo Heberu 8:11 ni o tọ