Heberu 8:9 BM

9 Kì í ṣe irú majẹmu tí mo bá àwọn baba wọn dání ọjọ́ tí mo fà wọ́n lọ́wọ́ jáde kúrò ní ilẹ̀ Ijipti.Nítorí wọn kò pa majẹmu mi mọ́,mo bá kẹ̀yìn sí wọn.

Ka pipe ipin Heberu 8

Wo Heberu 8:9 ni o tọ