17 Ìwé ìpíngún kò wúlò níwọ̀n ìgbà tí ẹni tí ó ṣe é bá wà láàyè. Ó di ìgbà tí ó bá kú.
Ka pipe ipin Heberu 9
Wo Heberu 9:17 ni o tọ