Ìṣe Àwọn Aposteli 1:13 BM

13 Nígbà tí wọ́n wọ inú ilé, wọ́n lọ sí iyàrá òkè níbi tí wọn ń gbé. Àwọn tí wọ́n jọ ń gbé ni Peteru, Johanu, Jakọbu, Anderu, Filipi, Tomasi, Batolomiu, Matiu, Jakọbu ọmọ Alfeu, Simoni ti ẹgbẹ́ Seloti ati Judasi ọmọ Jakọbu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 1:13 ni o tọ