Ìṣe Àwọn Aposteli 1:5 BM

5 Nítorí omi ni Johanu fi ń ṣe ìwẹ̀mọ́, ṣugbọn Ẹ̀mí Mímọ́ ni a óo fi ṣe ìwẹ̀mọ́ fun yín láìpẹ́ jọjọ.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 1:5 ni o tọ